-
Léfítíkù 27:11-13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Tó bá jẹ́ ẹran aláìmọ́,+ tí kò bójú mu ló mú wá láti fi ṣe ọrẹ fún Jèhófà, kó mú kí ẹran náà dúró níwájú àlùfáà. 12 Kí àlùfáà wá díye lé e, bó bá ṣe dáa tàbí bó ṣe burú sí. Iye tí àlùfáà bá dá lé e ni yóò jẹ́. 13 Àmọ́ tó bá tiẹ̀ fẹ́ rà á pa dà, ó gbọ́dọ̀ fi ìdá márùn-ún iye tí wọ́n dá lé e kún un.+
-