-
Diutarónómì 14:7, 8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Àmọ́, ẹ ò gbọ́dọ̀ jẹ àwọn ẹran yìí tí wọ́n ń jẹ àpọ̀jẹ tàbí tí pátákò wọn là nìkan: ràkúnmí, ehoro àti gara orí àpáta, torí pé wọ́n ń jẹ àpọ̀jẹ ṣùgbọ́n pátákò wọn ò là. Aláìmọ́ ni wọ́n jẹ́ fún yín.+ 8 Bákan náà ni ẹlẹ́dẹ̀, torí pátákò rẹ̀ là, àmọ́ kì í jẹ àpọ̀jẹ. Aláìmọ́ ló jẹ́ fún yín. Ẹ ò gbọ́dọ̀ jẹ ẹran wọn, ẹ ò sì gbọ́dọ̀ fọwọ́ kan òkú wọn.
-