-
Ẹ́kísódù 29:26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 “Kí o gé igẹ̀ àgbò àfiyanni náà,+ tí o fi rúbọ torí Áárónì, kí o sì fì í síwá-sẹ́yìn bí ọrẹ fífì níwájú Jèhófà, yóò sì di ìpín tìrẹ.
-
-
Léfítíkù 7:34Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
34 Torí mo mú igẹ̀ ọrẹ fífì àti ẹsẹ̀ ìpín mímọ́ náà látinú àwọn ẹbọ ìrẹ́pọ̀ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, mo sì fún àlùfáà Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀, kó jẹ́ ìlànà tó máa wà fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì+ títí lọ.
-