ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nọ́ńbà 26:62, 63
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 62 Gbogbo àwọn tí wọ́n forúkọ wọn sílẹ̀ jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́tàlélógún (23,000), gbogbo wọn jẹ́ ọkùnrin láti ọmọ oṣù kan sókè.+ Wọn ò forúkọ wọn sílẹ̀ pẹ̀lú ti àwọn ọmọ Ísírẹ́lì,+ torí wọn ò fún wọn ní ogún kankan láàárín àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.+

      63 Èyí ni àwọn tí Mósè àti àlùfáà Élíásárì forúkọ wọn sílẹ̀ nígbà tí wọ́n forúkọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sílẹ̀ ní aṣálẹ̀ tó tẹ́jú ní Móábù, nítòsí Jọ́dánì ní Jẹ́ríkò.

  • Diutarónómì 10:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Ìdí nìyẹn tí wọn ò fi fún Léfì ní ìpín tàbí ogún kankan pẹ̀lú àwọn arákùnrin rẹ̀. Jèhófà ni ogún rẹ̀, bí Jèhófà Ọlọ́run rẹ ṣe sọ fún un.+

  • Diutarónómì 14:27
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 27 O ò gbọ́dọ̀ gbàgbé ọmọ Léfì tó wà nínú àwọn ìlú rẹ,+ torí wọn ò fún un ní ìpín tàbí ogún kankan pẹ̀lú rẹ.+

  • Jóṣúà 14:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Mósè ti pín ogún fún ẹ̀yà méjì àtààbọ̀ yòókù ní òdìkejì* Jọ́dánì,+ àmọ́ kò pín ogún kankan fún àwọn ọmọ Léfì láàárín wọn.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́