Jóṣúà 13:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Àmọ́ Mósè ò fún ẹ̀yà àwọn ọmọ Léfì ní ogún kankan.+ Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì ni ogún wọn, bó ṣe ṣèlérí fún wọn.+
33 Àmọ́ Mósè ò fún ẹ̀yà àwọn ọmọ Léfì ní ogún kankan.+ Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì ni ogún wọn, bó ṣe ṣèlérí fún wọn.+