-
Léfítíkù 15:31Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
31 “‘Bí o ṣe máa ya àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sọ́tọ̀ kúrò nínú àìmọ́ wọn nìyẹn, kí wọ́n má bàa kú nínú àìmọ́ wọn torí wọ́n sọ àgọ́ ìjọsìn mi tó wà láàárín wọn+ di ẹlẹ́gbin.
-