Sáàmù 51:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Fi hísópù wẹ̀ mí mọ́ kúrò nínú ẹ̀ṣẹ̀ mi, kí n lè mọ́;+Wẹ̀ mí, kí n lè funfun ju yìnyín lọ.+