51 torí pé ẹ̀yin méjèèjì kò jẹ́ olóòótọ́ sí mi láàárín àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, níbi omi Mẹ́ríbà+ ti Kádéṣì ní aginjù Síínì, torí pé ẹ ò fi hàn pé mo jẹ́ mímọ́ lójú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.+ 52 Ọ̀ọ́kán ni wàá ti rí ilẹ̀ náà, àmọ́ o ò ní wọ ilẹ̀ tí mo fẹ́ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.”+