4 Jèhófà sọ fún un pé: “Ilẹ̀ tí mo búra nípa rẹ̀ fún Ábúráhámù, Ísákì àti Jékọ́bù nìyí pé, ‘Ọmọ rẹ ni èmi yóò fún.’+ Mo ti jẹ́ kí o fi ojú ara rẹ rí i, àmọ́ o ò ní sọdá sí ibẹ̀.”+
5 Lẹ́yìn náà, Mósè ìránṣẹ́ Jèhófà kú síbẹ̀ ní ilẹ̀ Móábù bí Jèhófà ṣe sọ gẹ́lẹ́.+