ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nọ́ńbà 20:24
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 24 “Wọ́n máa kó Áárónì jọ pẹ̀lú àwọn èèyàn rẹ̀.*+ Kò ní wọ ilẹ̀ tí màá fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, torí pé ẹ̀yin méjèèjì ṣe ohun tó lòdì sí àṣẹ tí mo pa nípa omi Mẹ́ríbà.+

  • Nọ́ńbà 20:28
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Mósè wá bọ́ aṣọ lọ́rùn Áárónì, ó sì wọ̀ ọ́ fún Élíásárì ọmọ rẹ̀. Lẹ́yìn náà, Áárónì kú síbẹ̀, lórí òkè+ náà. Mósè àti Élíásárì sì sọ̀ kalẹ̀ láti orí òkè náà.

  • Nọ́ńbà 33:38
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 38 Àlùfáà Áárónì wá gun Òkè Hóórì lọ bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ, ó sì kú síbẹ̀ ní ọjọ́ kìíní, oṣù+ karùn-ún, ọdún ogójì tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì.

  • Diutarónómì 10:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 “Lẹ́yìn náà, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì gbéra ní Béérótì Bene-jáákánì lọ sí Mósírà. Ibẹ̀ ni Áárónì kú sí, ibẹ̀ sì ni wọ́n sin ín sí,+ Élíásárì ọmọ rẹ̀ wá di àlùfáà dípò rẹ̀.+

  • Diutarónómì 32:50
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 50 O máa kú sórí òkè tí o fẹ́ gùn yìí, a ó sì kó ọ jọ pẹ̀lú àwọn èèyàn rẹ,* bí Áárónì ẹ̀gbọ́n rẹ ṣe kú sórí Òkè Hóórì+ gẹ́lẹ́, tí wọ́n sì kó o jọ pẹ̀lú àwọn èèyàn rẹ̀,

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́