-
Nọ́ńbà 21:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Wọ́n kúrò níbẹ̀, wọ́n sì pàgọ́ sí agbègbè Áánónì,+ tó wà ní aginjù tó bẹ̀rẹ̀ láti ààlà àwọn Ámórì, torí Áánónì ni ààlà Móábù, láàárín Móábù àti àwọn Ámórì.
-
-
Diutarónómì 3:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Mo sì ti fún àwọn ọmọ Rúbẹ́nì àti àwọn ọmọ Gádì+ ní Gílíádì títí dé Àfonífojì Áánónì, àárín àfonífojì náà sì ni ààlà rẹ̀, títí lọ dé Jábókù, àfonífojì tó jẹ́ ààlà àwọn ọmọ Ámónì,
-