ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nọ́ńbà 31:7, 8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Wọ́n bá Mídíánì jagun, bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ fún Mósè gẹ́lẹ́, wọ́n sì pa gbogbo ọkùnrin. 8 Yàtọ̀ sí àwọn tí wọ́n pa, wọ́n tún pa àwọn ọba Mídíánì, ìyẹn Éfì, Rékémù, Súúrì, Húrì àti Rébà, àwọn ọba Mídíánì márààrún. Wọ́n tún fi idà pa Báláámù+ ọmọ Béórì.

  • Jóṣúà 13:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Mósè pín ogún fún ẹ̀yà àwọn ọmọ Rúbẹ́nì ní ìdílé-ìdílé,

  • Jóṣúà 13:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 gbogbo ìlú tó wà lórí ilẹ̀ tó tẹ́jú àti gbogbo ilẹ̀ Síhónì ọba àwọn Ámórì, tó jọba ní Hẹ́ṣíbónì.+ Mósè ṣẹ́gun òun+ àtàwọn ìjòyè Mídíánì, ìyẹn Éfì, Rékémù, Súúrì, Húrì àti Rébà,+ àwọn ọba tó wà lábẹ́ Síhónì, tí wọ́n ń gbé ilẹ̀ náà.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́