Nọ́ńbà 24:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 ‘Bí Bálákì bá tiẹ̀ fún mi ní ilé rẹ̀ tí fàdákà àti wúrà kún inú rẹ̀, mi ò kàn ní ṣe ohunkóhun tó wù mí,* tó lòdì sí àṣẹ Jèhófà, bóyá ó dáa tàbí kò dáa. Ọ̀rọ̀ tí Jèhófà bá sọ fún mi nìkan ni màá sọ’?+
13 ‘Bí Bálákì bá tiẹ̀ fún mi ní ilé rẹ̀ tí fàdákà àti wúrà kún inú rẹ̀, mi ò kàn ní ṣe ohunkóhun tó wù mí,* tó lòdì sí àṣẹ Jèhófà, bóyá ó dáa tàbí kò dáa. Ọ̀rọ̀ tí Jèhófà bá sọ fún mi nìkan ni màá sọ’?+