-
Nọ́ńbà 22:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Àmọ́ Báláámù dá àwọn ìránṣẹ́ Bálákì lóhùn pé: “Bí Bálákì bá tiẹ̀ fún mi ní ilé rẹ̀ tí fàdákà àti wúrà kún inú rẹ̀, mi ò ní ṣe ohunkóhun tó ta ko àṣẹ Jèhófà Ọlọ́run mi, bó ti wù kó kéré tàbí kó pọ̀ tó.+
-
-
Nọ́ńbà 22:38Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
38 Báláámù dá Bálákì lóhùn pé: “Ó dáa, mo ṣáà ti dé báyìí. Àmọ́ ṣé mo wá lè dá sọ ohunkóhun? Ọ̀rọ̀ tí Ọlọ́run bá fi sí mi lẹ́nu+ nìkan ni màá sọ.”
-