-
Nọ́ńbà 22:41Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
41 Nígbà tí ilẹ̀ mọ́, Bálákì mú Báláámù gòkè lọ sí Bamoti-báálì; ibẹ̀ ló ti rí gbogbo àwọn èèyàn náà.+
-
-
Nọ́ńbà 23:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Báláámù wá sọ fún Bálákì pé: “Mọ pẹpẹ+ méje sí ibí yìí, kí o sì ṣètò akọ màlúù méje àti àgbò méje sílẹ̀ fún mi.”
-