Nọ́ńbà 21:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Láti Bámótì, wọ́n lọ sí àfonífojì tó wà ní agbègbè* Móábù,+ ní òkè Písígà,+ tó kọjú sí Jéṣímónì.*+
20 Láti Bámótì, wọ́n lọ sí àfonífojì tó wà ní agbègbè* Móábù,+ ní òkè Písígà,+ tó kọjú sí Jéṣímónì.*+