Diutarónómì 3:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Gun orí Písígà lọ,+ kí o wo ìwọ̀ oòrùn, àríwá, gúúsù àti ìlà oòrùn, kí o sì fi ojú ara rẹ rí ilẹ̀ náà, torí pé o ò ní sọdá Jọ́dánì yìí.+ Diutarónómì 34:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Mósè wá kúrò ní aṣálẹ̀ tó tẹ́jú ní Móábù lọ sí Òkè Nébò,+ sí orí Písígà,+ tó dojú kọ Jẹ́ríkò.+ Jèhófà sì fi gbogbo ilẹ̀ náà hàn án, láti Gílíádì títí dé Dánì+
27 Gun orí Písígà lọ,+ kí o wo ìwọ̀ oòrùn, àríwá, gúúsù àti ìlà oòrùn, kí o sì fi ojú ara rẹ rí ilẹ̀ náà, torí pé o ò ní sọdá Jọ́dánì yìí.+
34 Mósè wá kúrò ní aṣálẹ̀ tó tẹ́jú ní Móábù lọ sí Òkè Nébò,+ sí orí Písígà,+ tó dojú kọ Jẹ́ríkò.+ Jèhófà sì fi gbogbo ilẹ̀ náà hàn án, láti Gílíádì títí dé Dánì+