ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nọ́ńbà 23:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Báláámù wá sọ fún Bálákì pé: “Dúró síbí, nídìí ẹbọ sísun rẹ, èmi á sì lọ. Bóyá Jèhófà máa kàn sí mi. Màá jẹ́ kí o mọ ohunkóhun tó bá fi hàn mí.” Ó wá lọ sórí òkè kan tí ohunkóhun kò hù níbẹ̀.

  • Nọ́ńbà 23:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Báláámù wá sọ fún Bálákì pé: “Dúró síbí, nídìí ẹbọ sísun rẹ, sì jẹ́ kí n kàn sí I níbẹ̀ yẹn.”

  • Nọ́ńbà 23:23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 Torí kò sí ẹni tó lè ríran ìparun sí Jékọ́bù,+

      Bẹ́ẹ̀ ni ẹnikẹ́ni kò lè woṣẹ́ ibi sí Ísírẹ́lì.+

      Ní àkókò yìí, wọ́n á máa sọ nípa Jékọ́bù àti Ísírẹ́lì pé:

      ‘Ẹ wo ohun tí Ọlọ́run ṣe!’

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́