Nọ́ńbà 1:52 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 52 “Kí ọmọ Ísírẹ́lì kọ̀ọ̀kan pa àgọ́ rẹ̀ sí ibi tí wọ́n yàn fún un, ọkùnrin kọ̀ọ̀kan níbi tí wọ́n pín àwọn ẹ̀yà sí ní mẹ́ta-mẹ́ta,*+ ní àwùjọ-àwùjọ.* Nọ́ńbà 2:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Kí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pàgọ́ síbi tí wọ́n pín àwọn ẹ̀yà wọn sí ní mẹ́ta-mẹ́ta,+ kí ọkùnrin kọ̀ọ̀kan pàgọ́ síbi àkọlé* agbo ilé bàbá rẹ̀. Kí àgọ́ wọn dojú kọ àgọ́ ìpàdé, kí wọ́n pàgọ́ yí i ká.
52 “Kí ọmọ Ísírẹ́lì kọ̀ọ̀kan pa àgọ́ rẹ̀ sí ibi tí wọ́n yàn fún un, ọkùnrin kọ̀ọ̀kan níbi tí wọ́n pín àwọn ẹ̀yà sí ní mẹ́ta-mẹ́ta,*+ ní àwùjọ-àwùjọ.*
2 “Kí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pàgọ́ síbi tí wọ́n pín àwọn ẹ̀yà wọn sí ní mẹ́ta-mẹ́ta,+ kí ọkùnrin kọ̀ọ̀kan pàgọ́ síbi àkọlé* agbo ilé bàbá rẹ̀. Kí àgọ́ wọn dojú kọ àgọ́ ìpàdé, kí wọ́n pàgọ́ yí i ká.