2 Sámúẹ́lì 8:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ó ṣẹ́gun àwọn ọmọ Móábù,+ ó dá wọn dùbúlẹ̀, ó sì fi okùn wọ̀n wọ́n. Ó ní kí wọ́n pa àwọn tó wà níbi tí okùn ìwọ̀n méjì gùn dé, àmọ́ kí wọ́n dá àwọn tó wà níbi okùn ìwọ̀n kan sí.+ Àwọn ọmọ Móábù di ìránṣẹ́ Dáfídì, wọ́n sì ń mú ìṣákọ́lẹ̀*+ wá. 1 Kíróníkà 18:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Lẹ́yìn náà, Dáfídì ṣẹ́gun Móábù,+ àwọn ọmọ Móábù wá di ìránṣẹ́ rẹ̀, wọ́n sì ń mú ìṣákọ́lẹ̀*+ wá. Sáàmù 108:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Móábù ni bàsíà tí mo fi ń wẹ ẹsẹ̀.+ Orí Édómù ni màá ju bàtà mi sí.+ Màá kígbe ìṣẹ́gun lórí Filísíà.”+
2 Ó ṣẹ́gun àwọn ọmọ Móábù,+ ó dá wọn dùbúlẹ̀, ó sì fi okùn wọ̀n wọ́n. Ó ní kí wọ́n pa àwọn tó wà níbi tí okùn ìwọ̀n méjì gùn dé, àmọ́ kí wọ́n dá àwọn tó wà níbi okùn ìwọ̀n kan sí.+ Àwọn ọmọ Móábù di ìránṣẹ́ Dáfídì, wọ́n sì ń mú ìṣákọ́lẹ̀*+ wá.
9 Móábù ni bàsíà tí mo fi ń wẹ ẹsẹ̀.+ Orí Édómù ni màá ju bàtà mi sí.+ Màá kígbe ìṣẹ́gun lórí Filísíà.”+