18 Ní ọjọ́ yẹn, Jèhófà bá Ábúrámù dá májẹ̀mú+ kan pé: “Ọmọ* rẹ ni èmi yóò fún ní ilẹ̀ yìí,+ láti odò Íjíbítì dé odò ńlá náà, ìyẹn odò Yúfírétì:+19 ilẹ̀ àwọn Kénì,+ àwọn ọmọ Kénásì, àwọn Kádímónì,
16 Àtọmọdọ́mọ àwọn Kénì,+ tó jẹ́ bàbá ìyàwó Mósè+ pẹ̀lú àwọn èèyàn Júdà wá láti ìlú ọlọ́pẹ+ sí aginjù Júdà, tó wà ní gúúsù Árádì.+ Wọ́n lọ síbẹ̀, wọ́n sì ń gbé láàárín àwọn èèyàn náà.+