Nọ́ńbà 25:14, 15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ó ṣẹlẹ̀ pé, orúkọ ọmọ Ísírẹ́lì tí wọ́n pa pẹ̀lú ọmọbìnrin Mídíánì náà ni Símírì ọmọ Sálù, ìjòyè agbo ilé bàbá àwọn ọmọ Síméónì. 15 Orúkọ obìnrin ọmọ Mídíánì tí wọ́n pa ni Kọ́síbì ọmọ Súúrì+ tó jẹ́ olórí àwọn agbo ilé, ní ìdílé kan ní Mídíánì.+
14 Ó ṣẹlẹ̀ pé, orúkọ ọmọ Ísírẹ́lì tí wọ́n pa pẹ̀lú ọmọbìnrin Mídíánì náà ni Símírì ọmọ Sálù, ìjòyè agbo ilé bàbá àwọn ọmọ Síméónì. 15 Orúkọ obìnrin ọmọ Mídíánì tí wọ́n pa ni Kọ́síbì ọmọ Súúrì+ tó jẹ́ olórí àwọn agbo ilé, ní ìdílé kan ní Mídíánì.+