1 Kíróníkà 1:32, 33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Àwọn ọmọ tí Kétúrà,+ wáhàrì* Ábúráhámù bí ni Símíránì, Jókíṣánì, Médánì, Mídíánì,+ Íṣíbákì àti Ṣúáhì.+ Àwọn ọmọ Jókíṣánì ni Ṣébà àti Dédánì.+ 33 Àwọn ọmọ Mídíánì ni Eéfà,+ Éférì, Hánókù, Ábíídà àti Élídáà. Ọmọ Kétúrà ni gbogbo wọn.
32 Àwọn ọmọ tí Kétúrà,+ wáhàrì* Ábúráhámù bí ni Símíránì, Jókíṣánì, Médánì, Mídíánì,+ Íṣíbákì àti Ṣúáhì.+ Àwọn ọmọ Jókíṣánì ni Ṣébà àti Dédánì.+ 33 Àwọn ọmọ Mídíánì ni Eéfà,+ Éférì, Hánókù, Ábíídà àti Élídáà. Ọmọ Kétúrà ni gbogbo wọn.