ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Kíróníkà 6:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Élíásárì bí Fíníhásì;+ Fíníhásì bí Ábíṣúà.

  • Ẹ́sírà 7:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Lẹ́yìn àwọn nǹkan yìí, nígbà ìjọba Atasásítà+ ọba Páṣíà, Ẹ́sírà*+ pa dà. Ẹ́sírà jẹ́ ọmọ Seráyà,+ ọmọ Asaráyà, ọmọ Hilikáyà,+

  • Ẹ́sírà 7:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 ọmọ Ábíṣúà, ọmọ Fíníhásì,+ ọmọ Élíásárì,+ ọmọ Áárónì+ olórí àlùfáà.

  • Ẹ́sírà 8:1, 2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Àwọn olórí agbo ilé àti àkọsílẹ̀ orúkọ ìdílé àwọn tó tẹ̀ lé mi jáde kúrò ní Bábílónì nígbà ìjọba Ọba Atasásítà nìyí:+ 2 Gẹ́ṣómù, látinú àwọn ọmọ Fíníhásì;+ Dáníẹ́lì, látinú àwọn ọmọ Ítámárì;+ Hátúṣì, látinú àwọn ọmọ Dáfídì;

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́