Nọ́ńbà 20:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Kí o bọ́ aṣọ+ ọrùn Áárónì, kí o sì wọ̀ ọ́ fún Élíásárì+ ọmọ rẹ̀, ibẹ̀ ni Áárónì máa kú sí.”*