Ẹ́kísódù 6:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Àwọn ọmọ Kórà ni Ásírì, Ẹlikénà àti Ábíásáfù.+ Ìdílé àwọn ọmọ Kórà+ nìyí. Nọ́ńbà 26:58 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 58 Àwọn ìdílé àwọn ọmọ Léfì nìyí: ìdílé àwọn ọmọ Líbínì,+ ìdílé àwọn ọmọ Hébúrónì,+ ìdílé àwọn ọmọ Máhílì,+ ìdílé àwọn ọmọ Múṣì,+ ìdílé àwọn ọmọ Kórà. Kóhátì+ bí Ámúrámù.+ Sáàmù 42:àkọlé Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun Sí olùdarí. Másíkílì* àwọn ọmọ Kórà.+
58 Àwọn ìdílé àwọn ọmọ Léfì nìyí: ìdílé àwọn ọmọ Líbínì,+ ìdílé àwọn ọmọ Hébúrónì,+ ìdílé àwọn ọmọ Máhílì,+ ìdílé àwọn ọmọ Múṣì,+ ìdílé àwọn ọmọ Kórà. Kóhátì+ bí Ámúrámù.+