Nọ́ńbà 26:10, 11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ilẹ̀ lanu,* ó sì gbé wọn mì. Ní ti Kórà, òun àtàwọn tó ń tì í lẹ́yìn kú nígbà tí iná jó igba ó lé àádọ́ta (250) ọkùnrin+ run. Wọ́n wá di àpẹẹrẹ tó jẹ́ ìkìlọ̀.+ 11 Àmọ́, àwọn ọmọ Kórà kò kú.+
10 Ilẹ̀ lanu,* ó sì gbé wọn mì. Ní ti Kórà, òun àtàwọn tó ń tì í lẹ́yìn kú nígbà tí iná jó igba ó lé àádọ́ta (250) ọkùnrin+ run. Wọ́n wá di àpẹẹrẹ tó jẹ́ ìkìlọ̀.+ 11 Àmọ́, àwọn ọmọ Kórà kò kú.+