Jẹ́nẹ́sísì 29:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Ó tún lóyún lẹ́ẹ̀kan sí i, ó bí ọmọkùnrin kan, ó sì sọ pé: “Lọ́tẹ̀ yìí, màá yin Jèhófà.” Torí náà, ó pe orúkọ rẹ̀ ní Júdà.*+ Lẹ́yìn ìyẹn, kò bímọ mọ́. Jẹ́nẹ́sísì 46:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Àwọn ọmọ Júdà+ ni Éérì, Ónánì, Ṣélà,+ Pérésì+ àti Síírà.+ Àmọ́ Éérì àti Ónánì kú ní ilẹ̀ Kénáánì.+ Àwọn ọmọ Pérésì ni Hésírónì àti Hámúlù.+
35 Ó tún lóyún lẹ́ẹ̀kan sí i, ó bí ọmọkùnrin kan, ó sì sọ pé: “Lọ́tẹ̀ yìí, màá yin Jèhófà.” Torí náà, ó pe orúkọ rẹ̀ ní Júdà.*+ Lẹ́yìn ìyẹn, kò bímọ mọ́.
12 Àwọn ọmọ Júdà+ ni Éérì, Ónánì, Ṣélà,+ Pérésì+ àti Síírà.+ Àmọ́ Éérì àti Ónánì kú ní ilẹ̀ Kénáánì.+ Àwọn ọmọ Pérésì ni Hésírónì àti Hámúlù.+