-
Jẹ́nẹ́sísì 35:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Àwọn ọmọkùnrin tí Líà bí ni Rúbẹ́nì+ tó jẹ́ àkọ́bí Jékọ́bù, lẹ́yìn náà, ó bí Síméónì, Léfì, Júdà, Ísákà àti Sébúlúnì.
-
-
Jẹ́nẹ́sísì 37:26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 Ni Júdà bá sọ fún àwọn arákùnrin rẹ̀ pé: “Àǹfààní wo ló máa ṣe wá tá a bá pa àbúrò wa, tí a sì bo ẹ̀jẹ̀+ rẹ̀ mọ́lẹ̀?
-
-
Jẹ́nẹ́sísì 44:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Júdà wá sún mọ́ ọn, ó sì sọ pé: “Mo bẹ̀ ọ́, ọ̀gá mi, jọ̀ọ́ jẹ́ kí ẹrú rẹ sọ̀rọ̀ kan létí ọ̀gá mi, má sì bínú sí ẹrú rẹ, torí bíi Fáráò lo jẹ́.+
-