Jẹ́nẹ́sísì 38:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Àmọ́ bó ṣe fa ọwọ́ rẹ̀ pa dà, arákùnrin rẹ̀ jáde, obìnrin náà sì sọ pé: “Wo bí o ṣe dọ́gbẹ́ sí ìyá rẹ lára kí o tó lè jáde!” Torí náà, wọ́n pe orúkọ rẹ̀ ní Pérésì.*+ Rúùtù 4:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ìlà ìdílé* Pérésì+ nìyí: Pérésì bí Hésírónì;+ Mátíù 1:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Támárì bí Pérésì àti Síírà+ fún Júdà;Pérésì bí Hésírónì;+Hésírónì bí Rámù;+
29 Àmọ́ bó ṣe fa ọwọ́ rẹ̀ pa dà, arákùnrin rẹ̀ jáde, obìnrin náà sì sọ pé: “Wo bí o ṣe dọ́gbẹ́ sí ìyá rẹ lára kí o tó lè jáde!” Torí náà, wọ́n pe orúkọ rẹ̀ ní Pérésì.*+