-
Mátíù 1:2-6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Ísákì bí Jékọ́bù;+
Jékọ́bù bí Júdà+ àti àwọn arákùnrin rẹ̀;
3 Támárì bí Pérésì àti Síírà+ fún Júdà;
Pérésì bí Hésírónì;+
Hésírónì bí Rámù;+
4 Rámù bí Ámínádábù;
Ámínádábù bí Náṣónì;+
Náṣónì bí Sálímọ́nì;
5 Ráhábù+ bí Bóásì fún Sálímọ́nì;
Rúùtù bí Óbédì fún Bóásì;+
Óbédì bí Jésè;+
Ìyàwó Ùráyà bí Sólómọ́nì+ fún Dáfídì;
-