29 Àmọ́ bó ṣe fa ọwọ́ rẹ̀ pa dà, arákùnrin rẹ̀ jáde, obìnrin náà sì sọ pé: “Wo bí o ṣe dọ́gbẹ́ sí ìyá rẹ lára kí o tó lè jáde!” Torí náà, wọ́n pe orúkọ rẹ̀ ní Pérésì.*+
20 Àwọn ọmọ Júdà nìyí ní ìdílé-ìdílé: látọ̀dọ̀ Ṣélà,+ ìdílé àwọn ọmọ Ṣélà; látọ̀dọ̀ Pérésì,+ ìdílé àwọn ọmọ Pérésì; látọ̀dọ̀ Síírà,+ ìdílé àwọn ọmọ Síírà.