Jeremáyà 32:37 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 37 ‘Wò ó, màá kó wọn jọ láti inú gbogbo ilẹ̀ tí mo fọ́n wọn ká sí nínú ìbínú mi àti nínú ìrunú mi àti nínú ìkannú ńlá mi,+ màá sì mú wọn pa dà wá sí ibí yìí láti máa gbé lábẹ́ ààbò.+ Jeremáyà 32:41 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 41 Ṣe ni inú mi á máa dùn nítorí wọn láti máa ṣe rere fún wọn,+ màá sì fi gbogbo ọkàn mi àti gbogbo ara* mi gbìn wọ́n sí ilẹ̀ yìí.’”+
37 ‘Wò ó, màá kó wọn jọ láti inú gbogbo ilẹ̀ tí mo fọ́n wọn ká sí nínú ìbínú mi àti nínú ìrunú mi àti nínú ìkannú ńlá mi,+ màá sì mú wọn pa dà wá sí ibí yìí láti máa gbé lábẹ́ ààbò.+
41 Ṣe ni inú mi á máa dùn nítorí wọn láti máa ṣe rere fún wọn,+ màá sì fi gbogbo ọkàn mi àti gbogbo ara* mi gbìn wọ́n sí ilẹ̀ yìí.’”+