Àìsáyà 65:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Inú mi máa dùn nínú Jerúsálẹ́mù, màá sì yọ̀ torí àwọn èèyàn mi;+A ò ní gbọ́ igbe ẹkún tàbí igbe ìdààmú nínú rẹ̀ mọ́.”+ Sefanáyà 3:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Jèhófà Ọlọ́run rẹ wà ní àárín rẹ.+ Ó máa gbani là bí Alágbára ńlá. Ó máa yọ̀ gidigidi nítorí rẹ.+ Á dákẹ́ jẹ́ẹ́* nínú ìfẹ́ rẹ̀. Á dunnú nítorí rẹ pẹ̀lú igbe ayọ̀.
19 Inú mi máa dùn nínú Jerúsálẹ́mù, màá sì yọ̀ torí àwọn èèyàn mi;+A ò ní gbọ́ igbe ẹkún tàbí igbe ìdààmú nínú rẹ̀ mọ́.”+
17 Jèhófà Ọlọ́run rẹ wà ní àárín rẹ.+ Ó máa gbani là bí Alágbára ńlá. Ó máa yọ̀ gidigidi nítorí rẹ.+ Á dákẹ́ jẹ́ẹ́* nínú ìfẹ́ rẹ̀. Á dunnú nítorí rẹ pẹ̀lú igbe ayọ̀.