-
Àìsáyà 62:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Àmọ́ wọ́n máa pè ọ́ ní Inú Mi Dùn sí I,+
Wọ́n sì máa pe ilẹ̀ rẹ ní Èyí Tí A Gbé Níyàwó.
Torí inú Jèhófà máa dùn sí ọ,
Ilẹ̀ rẹ sì máa dà bí èyí tí a gbé níyàwó.
-