Jóṣúà 1:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Jẹ́ onígboyà àti alágbára,+ torí ìwọ lo máa mú kí àwọn èèyàn yìí jogún ilẹ̀ tí mo búra fún àwọn baba ńlá wọn pé màá fún wọn.+ Sáàmù 27:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà;+Ní ìgboyà, kí o sì mọ́kàn le.+ Bẹ́ẹ̀ ni, gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà. Sáàmù 118:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Jèhófà wà lẹ́yìn mi; mi ò ní bẹ̀rù.+ Kí ni èèyàn lè fi mí ṣe?+
6 Jẹ́ onígboyà àti alágbára,+ torí ìwọ lo máa mú kí àwọn èèyàn yìí jogún ilẹ̀ tí mo búra fún àwọn baba ńlá wọn pé màá fún wọn.+