Àìsáyà 51:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 “Èmi fúnra mi ni Ẹni tó ń tù yín nínú.+ Ṣé ó wá yẹ kí ẹ máa bẹ̀rù ẹni kíkú tó máa kú+Àti ọmọ aráyé tó máa rọ bíi koríko tútù? Róòmù 8:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Kí ni ká wá sọ sọ́rọ̀ yìí? Tí Ọlọ́run bá wà lẹ́yìn wa, ta ló lè dènà wa?+ Hébérù 13:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ká lè nígboyà gidigidi, ká sì sọ pé: “Jèhófà* ni olùrànlọ́wọ́ mi; mi ò ní bẹ̀rù. Kí ni èèyàn lè fi mí ṣe?”+
12 “Èmi fúnra mi ni Ẹni tó ń tù yín nínú.+ Ṣé ó wá yẹ kí ẹ máa bẹ̀rù ẹni kíkú tó máa kú+Àti ọmọ aráyé tó máa rọ bíi koríko tútù?
6 Ká lè nígboyà gidigidi, ká sì sọ pé: “Jèhófà* ni olùrànlọ́wọ́ mi; mi ò ní bẹ̀rù. Kí ni èèyàn lè fi mí ṣe?”+