Sáàmù 118:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Jèhófà wà lẹ́yìn mi; mi ò ní bẹ̀rù.+ Kí ni èèyàn lè fi mí ṣe?+ 1 Jòhánù 4:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ẹ̀yin ọmọ kéékèèké, ọ̀dọ̀ Ọlọ́run lẹ ti wá, ẹ sì ti ṣẹ́gun wọn,+ torí ẹni tó wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú yín+ tóbi ju ẹni tó wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú ayé.+
4 Ẹ̀yin ọmọ kéékèèké, ọ̀dọ̀ Ọlọ́run lẹ ti wá, ẹ sì ti ṣẹ́gun wọn,+ torí ẹni tó wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú yín+ tóbi ju ẹni tó wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú ayé.+