Ẹ́kísódù 33:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ó sọ pé: “Èmi fúnra mi* yóò bá ọ lọ,+ màá sì fún ọ ní ìsinmi.”+