Diutarónómì 6:6, 7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Rí i pé o fi àwọn ọ̀rọ̀ yìí tí mò ń pa láṣẹ fún ọ lónìí sọ́kàn, 7 kí o máa fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ+ léraléra,* kí o sì máa sọ̀rọ̀ nípa rẹ̀ nígbà tí o bá jókòó nínú ilé rẹ, nígbà tí o bá ń rìn lójú ọ̀nà, nígbà tí o bá dùbúlẹ̀ àti nígbà tí o bá dìde.+ Éfésù 6:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ẹ̀yin bàbá, ẹ má ṣe máa mú àwọn ọmọ yín bínú,+ kàkà bẹ́ẹ̀, ẹ máa tọ́ wọn dàgbà nínú ìbáwí+ àti ìmọ̀ràn* Jèhófà.*+
6 Rí i pé o fi àwọn ọ̀rọ̀ yìí tí mò ń pa láṣẹ fún ọ lónìí sọ́kàn, 7 kí o máa fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ+ léraléra,* kí o sì máa sọ̀rọ̀ nípa rẹ̀ nígbà tí o bá jókòó nínú ilé rẹ, nígbà tí o bá ń rìn lójú ọ̀nà, nígbà tí o bá dùbúlẹ̀ àti nígbà tí o bá dìde.+
4 Ẹ̀yin bàbá, ẹ má ṣe máa mú àwọn ọmọ yín bínú,+ kàkà bẹ́ẹ̀, ẹ máa tọ́ wọn dàgbà nínú ìbáwí+ àti ìmọ̀ràn* Jèhófà.*+