Àìsáyà 1:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 O gbé! Ìwọ orílẹ̀-èdè ẹlẹ́ṣẹ̀,+Àwọn èèyàn tí ẹ̀ṣẹ̀ wọ̀ lọ́rùn,Ìran àwọn èèyàn burúkú, àwọn ọmọ oníwà ìbàjẹ́! Wọ́n ti fi Jèhófà sílẹ̀;+Wọ́n ti hùwà àfojúdi sí Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì;Wọ́n ti kẹ̀yìn sí i.
4 O gbé! Ìwọ orílẹ̀-èdè ẹlẹ́ṣẹ̀,+Àwọn èèyàn tí ẹ̀ṣẹ̀ wọ̀ lọ́rùn,Ìran àwọn èèyàn burúkú, àwọn ọmọ oníwà ìbàjẹ́! Wọ́n ti fi Jèhófà sílẹ̀;+Wọ́n ti hùwà àfojúdi sí Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì;Wọ́n ti kẹ̀yìn sí i.