Diutarónómì 31:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Jèhófà sọ fún Mósè pé: “Wò ó! O ò ní pẹ́ kú,* àwọn èèyàn yìí á sì bẹ̀rẹ̀ sí í bá àwọn ọlọ́run àjèjì tó yí wọn ká ní ilẹ̀ tí wọ́n ń lọ ṣe àgbèrè ẹ̀sìn.+ Wọ́n á pa mí tì,+ wọ́n á sì da májẹ̀mú mi tí mo bá wọn dá.+ Jeremáyà 2:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Ẹ̀sùn wo ni àwọn baba ńlá yín fi kàn mí,+Tí wọ́n fi lọ jìnnà kúrò lọ́dọ̀ mi,Tí wọ́n ń sin àwọn òrìṣà asán,+ tí àwọn fúnra wọn sì di asán?+
16 Jèhófà sọ fún Mósè pé: “Wò ó! O ò ní pẹ́ kú,* àwọn èèyàn yìí á sì bẹ̀rẹ̀ sí í bá àwọn ọlọ́run àjèjì tó yí wọn ká ní ilẹ̀ tí wọ́n ń lọ ṣe àgbèrè ẹ̀sìn.+ Wọ́n á pa mí tì,+ wọ́n á sì da májẹ̀mú mi tí mo bá wọn dá.+
5 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Ẹ̀sùn wo ni àwọn baba ńlá yín fi kàn mí,+Tí wọ́n fi lọ jìnnà kúrò lọ́dọ̀ mi,Tí wọ́n ń sin àwọn òrìṣà asán,+ tí àwọn fúnra wọn sì di asán?+