-
Sáàmù 106:37-39Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
37 Wọ́n ń fi àwọn ọmọkùnrin wọn
Àti àwọn ọmọbìnrin wọn rúbọ sí àwọn ẹ̀mí èṣù.+
38 Wọ́n ń ta ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ sílẹ̀,+
Ẹ̀jẹ̀ àwọn ọmọkùnrin wọn àti ti àwọn ọmọbìnrin wọn
Tí wọ́n fi rúbọ sí àwọn òrìṣà Kénáánì;+
Ilẹ̀ náà sì di ẹlẹ́gbin nítorí ìtàjẹ̀sílẹ̀.
39 Àwọn iṣẹ́ wọn sọ wọ́n di aláìmọ́,
Wọ́n sì ṣe àgbèrè ẹ̀sìn.+
-