Àìsáyà 1:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 O gbé! Ìwọ orílẹ̀-èdè ẹlẹ́ṣẹ̀,+Àwọn èèyàn tí ẹ̀ṣẹ̀ wọ̀ lọ́rùn,Ìran àwọn èèyàn burúkú, àwọn ọmọ oníwà ìbàjẹ́! Wọ́n ti fi Jèhófà sílẹ̀;+Wọ́n ti hùwà àfojúdi sí Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì;Wọ́n ti kẹ̀yìn sí i. Hósíà 13:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Àwọn ibi ìjẹko wọn tẹ́ wọn lọ́rùn,+Wọ́n yó, wọ́n sì ń gbéra ga. Torí náà, wọ́n gbàgbé mi.+
4 O gbé! Ìwọ orílẹ̀-èdè ẹlẹ́ṣẹ̀,+Àwọn èèyàn tí ẹ̀ṣẹ̀ wọ̀ lọ́rùn,Ìran àwọn èèyàn burúkú, àwọn ọmọ oníwà ìbàjẹ́! Wọ́n ti fi Jèhófà sílẹ̀;+Wọ́n ti hùwà àfojúdi sí Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì;Wọ́n ti kẹ̀yìn sí i.