ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 17:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Torí náà, kí wọ́n má ṣe rú ẹbọ mọ́ sí àwọn ẹ̀mí èṣù tó rí bí ewúrẹ́,*+ èyí tí wọ́n ń bá ṣèṣekúṣe.+ Kí èyí jẹ́ àṣẹ tó máa wà títí lọ fún yín, jálẹ̀ àwọn ìran yín.”’

  • Sáàmù 106:37
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 37 Wọ́n ń fi àwọn ọmọkùnrin wọn

      Àti àwọn ọmọbìnrin wọn rúbọ sí àwọn ẹ̀mí èṣù.+

  • 1 Kọ́ríńtì 10:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Bẹ́ẹ̀ kọ́; àmọ́ ohun tí mò ń sọ ni pé àwọn nǹkan tí àwọn orílẹ̀-èdè fi ń rúbọ, àwọn ẹ̀mí èṣù ni wọ́n fi ń rúbọ sí, kì í ṣe Ọlọ́run;+ mi ò sì fẹ́ kí ẹ di alájọpín pẹ̀lú àwọn ẹ̀mí èṣù.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́