Àìsáyà 1:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ẹ gbọ́, ẹ̀yin ọ̀run, sì fetí sílẹ̀, ìwọ ayé,+Torí Jèhófà ti sọ pé: “Mo ti tọ́ àwọn ọmọ,+ mo sì ti tọ́jú wọn dàgbà, Àmọ́ wọ́n ti ṣọ̀tẹ̀ sí mi.+
2 Ẹ gbọ́, ẹ̀yin ọ̀run, sì fetí sílẹ̀, ìwọ ayé,+Torí Jèhófà ti sọ pé: “Mo ti tọ́ àwọn ọmọ,+ mo sì ti tọ́jú wọn dàgbà, Àmọ́ wọ́n ti ṣọ̀tẹ̀ sí mi.+