2 Kíróníkà 36:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Nítorí náà, ó gbé ọba àwọn ará Kálídíà+ dìde sí wọn, ẹni tó fi idà pa àwọn ọ̀dọ́kùnrin wọn+ nínú ibi mímọ́ wọn;+ kò ṣàánú ọ̀dọ́kùnrin tàbí ọ̀dọ́bìnrin,* arúgbó tàbí aláàárẹ̀.+ Ohun gbogbo ni Ọlọ́run fi lé e lọ́wọ́.+ Ìdárò 2:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Òkú ọmọdékùnrin àti àgbà ọkùnrin wà nílẹ̀ ní àwọn ojú ọ̀nà.+ Àwọn wúńdíá* mi àti àwọn ọ̀dọ́kùnrin mi ni idà sì ti pa sílẹ̀.+ O ti pa wọ́n ní ọjọ́ ìbínú rẹ; o sì ti pa wọ́n láìṣàánú wọn.+
17 Nítorí náà, ó gbé ọba àwọn ará Kálídíà+ dìde sí wọn, ẹni tó fi idà pa àwọn ọ̀dọ́kùnrin wọn+ nínú ibi mímọ́ wọn;+ kò ṣàánú ọ̀dọ́kùnrin tàbí ọ̀dọ́bìnrin,* arúgbó tàbí aláàárẹ̀.+ Ohun gbogbo ni Ọlọ́run fi lé e lọ́wọ́.+
21 Òkú ọmọdékùnrin àti àgbà ọkùnrin wà nílẹ̀ ní àwọn ojú ọ̀nà.+ Àwọn wúńdíá* mi àti àwọn ọ̀dọ́kùnrin mi ni idà sì ti pa sílẹ̀.+ O ti pa wọ́n ní ọjọ́ ìbínú rẹ; o sì ti pa wọ́n láìṣàánú wọn.+