Náhúmù 1:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Jèhófà jẹ́ Ọlọ́run tó fẹ́ kí a máa jọ́sìn òun nìkan ṣoṣo,+ ó sì ń gbẹ̀san;Jèhófà ń gbẹ̀san, ó sì ṣe tán láti bínú.+ Jèhófà ń gbẹ̀san lára àwọn elénìní rẹ̀,Ó sì ń to ìbínú rẹ̀ jọ de àwọn ọ̀tá rẹ̀. Róòmù 12:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ẹ má ṣe fúnra yín gbẹ̀san, ẹ̀yin olùfẹ́, àmọ́ ẹ fàyè sílẹ̀ fún ìrunú;*+ nítorí ó ti wà lákọsílẹ̀ pé: “Tèmi ni ẹ̀san; màá gbẹ̀san, ni Jèhófà* wí.”+ Hébérù 10:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Torí a mọ Ẹni tó sọ pé: “Tèmi ni ẹ̀san; màá gbẹ̀san.” Àti pé: “Jèhófà* máa dá ẹjọ́ àwọn èèyàn rẹ̀.”+
2 Jèhófà jẹ́ Ọlọ́run tó fẹ́ kí a máa jọ́sìn òun nìkan ṣoṣo,+ ó sì ń gbẹ̀san;Jèhófà ń gbẹ̀san, ó sì ṣe tán láti bínú.+ Jèhófà ń gbẹ̀san lára àwọn elénìní rẹ̀,Ó sì ń to ìbínú rẹ̀ jọ de àwọn ọ̀tá rẹ̀.
19 Ẹ má ṣe fúnra yín gbẹ̀san, ẹ̀yin olùfẹ́, àmọ́ ẹ fàyè sílẹ̀ fún ìrunú;*+ nítorí ó ti wà lákọsílẹ̀ pé: “Tèmi ni ẹ̀san; màá gbẹ̀san, ni Jèhófà* wí.”+
30 Torí a mọ Ẹni tó sọ pé: “Tèmi ni ẹ̀san; màá gbẹ̀san.” Àti pé: “Jèhófà* máa dá ẹjọ́ àwọn èèyàn rẹ̀.”+