Sáàmù 73:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Bí ọ̀rọ̀ àwọn ẹni burúkú ṣe rí nìyí, àwọn tí gbogbo nǹkan dẹrùn fún.+ Wọ́n ń kó ọrọ̀ jọ ṣáá.+ Sáàmù 73:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ó dájú pé orí ilẹ̀ tó ń yọ̀ lo gbé wọn lé.+ Kí wọ́n lè ṣubú kí wọ́n sì pa run.+