-
Sáàmù 35:6, 7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Kí ọ̀nà wọn ṣókùnkùn, kí ó sì máa yọ̀ bọ̀rọ́
Bí áńgẹ́lì Jèhófà ṣe ń lépa wọn.
7 Nítorí pé wọ́n ti dẹ àwọ̀n dè mí láìnídìí;
Wọ́n ti gbẹ́ kòtò fún mi* láìnídìí.
-